Psalmu
Daf 117:1 YCE - Ẹ yìn Oluwa, gbogbo ẹnyin orilẹ-ède: ẹ yìn i, gbogbo enia.
Daf 117:2 YCE - Nitori ti ãnu rẹ̀ pọ̀ si wa: ati otitọ Oluwa
duro lailai. Yin OLUWA.