1 Kronika
3:1 Bayi wọnyi li awọn ọmọ Dafidi, ti a bi fun u ni Hebroni;
akọbi Amnoni, ti Ahinoamu ara Jesreeli; awọn keji Daniel, ti
Ábígẹ́lì ará Kámẹ́lì:
Ọba 3:2 YCE - Ẹkẹta, Absalomu ọmọ Maaka, ọmọbinrin Talmai ọba
Geṣuri: ẹkẹrin, Adonija ọmọ Hagiti.
Kro 3:3 YCE - Ẹkarun, Ṣefatiah ti Abitali: ẹkẹfa, Itreamu ti Egla aya rẹ̀.
3:4 Awọn mẹfa wọnyi li a bi fun u ni Hebroni; nibẹ li o si jọba li ọdun meje
ati oṣù mẹfa: o si jọba li ọdun mẹtalelọgbọn ni Jerusalemu.
3:5 Ati awọn wọnyi ni a bi fun u ni Jerusalemu; Ṣimea, ati Ṣobabu, ati
Natani, ati Solomoni, mẹrin, ti Batṣua, ọmọbinrin Ammieli:
Ọba 3:6 YCE - Ibhari pẹlu, ati Eliṣama, ati Elifeleti.
3:7 Ati Noga, ati Nefegi, ati Jafia.
3:8 Ati Eliṣama, ati Eliada, ati Elifeleti, mẹsan.
3:9 Wọnyi li gbogbo awọn ọmọ Dafidi, laika awọn ọmọ awọn obinrin, ati
Tamari arabinrin wọn.
Ọba 3:10 YCE - Ọmọ Solomoni si ni Rehoboamu, Abia ọmọ rẹ̀, Asa ọmọ rẹ̀, Jehoṣafati.
ọmọ rẹ,
3:11 Joramu ọmọ rẹ, Ahasiah ọmọ rẹ, Joaṣi ọmọ rẹ.
Ọba 3:12 YCE - Amasiah ọmọ rẹ̀, Asariah ọmọ rẹ̀, Jotamu ọmọ rẹ̀.
Ọba 3:13 YCE - Ahasi ọmọ rẹ̀, Hesekiah ọmọ rẹ̀, Manasse ọmọ rẹ̀.
3:14 Amoni ọmọ rẹ, Josiah ọmọ rẹ.
3:15 Ati awọn ọmọ Josiah, akọbi Johanani, awọn keji
Jehoiakimu, ẹkẹta Sedekiah, ẹkẹrin Ṣallumu.
3:16 Ati awọn ọmọ Jehoiakimu: Jekoniah ọmọ rẹ, Sedekiah ọmọ rẹ.
3:17 Ati awọn ọmọ Jekoniah; Assiri, Salatieli ọmọ rẹ̀,
3:18 Malkiramu pẹlu, ati Pedaiah, ati Ṣenasari, Jekamiah, Hoṣama, ati
Nedabiah.
3:19 Ati awọn ọmọ Pedaiah ni, Serubbabeli, ati Ṣimei: ati awọn ọmọ.
Serubabeli; Meṣullamu, ati Hananiah, ati Ṣelomiti arabinrin wọn.
3:20 Ati Haṣuba, ati Oheli, ati Berekiah, ati Hasadiah, Juṣabesedi, marun.
3:21 Ati awọn ọmọ Hananiah; Pelatiah, ati Jesaiah: awọn ọmọ Refaiah;
awọn ọmọ Arnani, awọn ọmọ Obadiah, awọn ọmọ Ṣekaniah.
3:22 Ati awọn ọmọ Ṣekaniah; Ṣemaiah: ati awọn ọmọ Ṣemaiah; Hattush,
ati Igeali, ati Bariah, ati Nearia, ati Ṣafati, mẹfa.
3:23 Ati awọn ọmọ Neariah; Elioenai, ati Hesekiah, ati Asrikamu, mẹta.
Ọba 3:24 YCE - Ati awọn ọmọ Elioenai ni Hodaiah, ati Eliaṣibu, ati Pelaiah, ati
Akubu, ati Johanani, ati Dalaiah, ati Anani, meje.